Olóṣèlú Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ike Omar Sanda Nwachukwu (ojoibi September 1, 1940)[1] jẹ́ ọmọ ológun tótifèyìntì àti olósèlú ará ilè Nàìjíríà tó di ọ̀pọ̀lọpọ̀ ipò mú ní ìjọba Nàìjírí̀a, ó di Alákòso Ọrọ òkèrè lẹ́ẹ̀mejì̀, Gómínà Ìpínlè Ímò àti Alágba nínú àwọn asojú Ilè-ìgbìmọ̀ Asòfin lati Ìpínlè Ábíá.
Ike Omar Sanda Nwachukwu | |
---|---|
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ímò | |
In office January 1984 – August 1985 | |
Asíwájú | Sam Mbakwe |
Arọ́pò | Allison Madueke |
Alákóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office December 1987 – December 1989 | |
Asíwájú | Bolaji Akinyemi |
Arọ́pò | Rilwan Lukman |
In office September 1990 – January 1993 | |
Asíwájú | Rilwan Lukman |
Arọ́pò | Matthew Mbu |
Alàgbà Aṣòfin fún Imo North | |
In office May 1999 – May 2003 | |
Arọ́pò | Uche Chukwumerije |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kẹ̀sán 1941 Port Harcourt, Nigeria |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.