![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/16/Ijebu_Ode%252C_Nigeria_-_panoramio_%25282%2529.jpg/640px-Ijebu_Ode%252C_Nigeria_-_panoramio_%25282%2529.jpg&w=640&q=50)
Ìjẹ̀bú-Òde
ẹkà ìjọba ìbílẹ̀ ti Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìjẹ̀bú-Òde jẹ́ ìlú tó gbajúmọ̀ nílẹ̀ Yorùbá ní Ìpínlẹ̀ Ògùn lápá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]. Ọba Awùjalẹ̀ ni orúkọ Ọba alạ́dé tí wọ́n fi ń jẹ ní Ìjẹ̀bú-Òde. Ọba Sikiru Kayode Adetona ni ó wà lórí ìtẹ́ lọ́wọ́ ní ìlú Ìjẹ̀bú-Òde.[2]
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/16/Ijebu_Ode%2C_Nigeria_-_panoramio_%282%29.jpg/640px-Ijebu_Ode%2C_Nigeria_-_panoramio_%282%29.jpg)
Quick Facts Ijebu-Ode, Country ...
Ijebu-Ode | |||
---|---|---|---|
| |||
![]() Aàfin ọba Ìjẹ̀bú Òde | |||
Coordinates: 6°49′15″N 3°55′15″E | |||
Country | ![]() | ||
State | Ogun | ||
Local Government Areas of Nigeria | Ijebu-Ode | ||
Government | |||
• Type | Democratic | ||
• Awujale | Oba Sikiru Kayode Adetona, Ogbagba Agbotewole II | ||
• Local Government Chairman | Emilola Gazal Babatunde (APC) | ||
Area | |||
• Total | 192 km2 (74 sq mi) | ||
Population (2006 Census) | |||
• Total | 222,653 | ||
Time zone | UTC+1 (WAT) | ||
3-digit postal code prefix | 120 | ||
Area code(s) | 120101 | ||
National language | Yorùbá | ||
|
Close