David Ejoor
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
David Akpode Ejoor RCDS, PSC, (10 January 1932 – 10 February 2019) jé̩ o̩mo̩ orílè̩-èdè Nàìjíríà,ó jẹ́ olórí Agbègbè àárín-Apá ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà té̩lè̩ kí ó tó di Ìpínlè̩ Bendel 1976. Ejoor tún jé̩ ọ̀gá àwọn ọmọọṣẹ́ Jagunjagun Orí-ilẹ̀ Nàìjíríà (COAS) láti ọdún 1971 di 1975.
Quick Facts Major General, Chief of Army Staff ...
Major General David Akpode Ejoor | |
---|---|
Fáìlì:Photo of David Akpode Ejoor.jpeg | |
Chief of Army Staff | |
In office January 1971 – 29 July 1975 | |
Asíwájú | Hassan Katsina |
Arọ́pò | Theophilus Danjuma |
Commandant of the Nigerian Defence Academy | |
In office January 1969 – January 1971 | |
Asíwájú | Brig M.R. Varma |
Arọ́pò | Maj-Gen. R.A. Adebayo |
Governor of Mid-Western Region | |
In office January 1966 – August 1967 | |
Asíwájú | Dennis Osadebay |
Arọ́pò | Sean Ikemefuna |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1932-01-10)10 Oṣù Kínní 1932.[1] Ovu, British Nigeria (now Delta State, Nigeria) |
Aláìsí | 10 February 2019(2019-02-10) (ọmọ ọdún 87) Lagos, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Unaffiliated |
Military service | |
Allegiance | ![]() |
Branch/service | ![]() |
Rank | ![]() |
Close