Chanel Simmonds
From Wikipedia, the free encyclopedia
Chanel Simmonds (tí wọ́n bí ní 10 August 1992) fìgbà kan jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orí tábìlì, ọmọ orílẹ̀-èdè South Africa .[1]
Quick Facts Orílẹ̀-èdè, Ọjọ́ìbí ...
Orílẹ̀-èdè | ![]() |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹjọ 1992 (1992-08-10) (ọmọ ọdún 31) Kempton Park, South Africa |
Ìga | 1.65 m (5 ft 5 in) |
Ọwọ́ ìgbáyò | Left-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | US$289,822 |
Iye ìdíje | 447–245 (64.6%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 23 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 158 (27 May 2013) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 1,360 (12 June 2023) |
Open Austrálíà | Q3 (2013) |
Open Fránsì | Q1 (2013, 2014) |
Wimbledon | Q2 (2012) |
Open Amẹ́ríkà | 1R (2013) |
Iye ìdíje | 278–184 (60.17%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 29 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 176 (26 August 2013) |
Fed Cup | 33–28 (54.1%) |
Close
Simmonds gba oyè mẹ́tàlélógún (23) to jẹ́ lórúkọ kan àti oyè mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) nínú oyè olórúkọ méjì ní May 2013, ìgbà náà sì ni ó gba ipò kejìdínlọ́gọ́jọ (158) ní àgbáyé. Ní 26 August 2013, ó gba ipò kẹrìndínlọ́gọ́sàn-án (176) ní WTA.[2]