From Wikipedia, the free encyclopedia
Brigitte Cuypers (tí wọ́n bí ní 3 December 1955) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orí tábìlì ti ilẹ̀ South Africa tó ti fẹ̀yìn tì.[2][3]
Orúkọ | Brigitte Cuypers-Fourie |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kejìlá 1955 Cape Town, South Africa |
Ìga | 1.69 m (5 ft 61⁄2 in)[1] |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed |
Iye ìdíje | no value |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 3 |
Open Fránsì | 3R (1977) |
Wimbledon | 3R (1978) |
Open Amẹ́ríkà | 3R (1977) |
Iye ìdíje | no value |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 3 |
Open Fránsì | 2R (1979) |
Wimbledon | QF (1977) |
Open Amẹ́ríkà | 3R (1977, 1978, 1979) |
Wimbledon | 3R (1977) |
Open Amẹ́ríkà | 2R (1978) |
Cuypers dé ipò àṣekágbá ti ìdíje South African Championships láti ọdún 1975 wọ 1979, ó sì gba oyè náà ní ọdún 1976, 1978 àti 1979. Ní ọdún 1977, ó gba oyè méjì nínú ìdíje Italian Open pẹ̀lú ẹni kejì rẹ̀, ìyẹn Marise Kruger.[3] Ní oṣù kẹjọ ọdún 1979, ó gbé ipòkejì nínú ìdíje Canadian Open, tí Laura duPont sì gbé ipò kìíní.[4]
Cuypers gba oyè ti ìdíje Rhodesian Open ní ọdún 1974 àti 1975.[5] Ó gba oyè méjì bákan náà ní ọdún 1979 nínú ìdíje Akron Virginia pẹ̀lú Mona Anne Guerrant.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.