Olóṣèlú Naijiria From Wikipedia, the free encyclopedia
Sen. Binos Dauda Yaroe jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Sénátọ̀ tí ó ń sójú agbègbè Adamawa South Senatorial District ti Ìpínlẹ̀ Adamawa[1] ní ilé ìgbìmò Aṣòfin àgbà lọ́wọ́lọ́wọ́.[2][3][4]
Binos Dauda Yaroe | |
---|---|
Sénátọ̀ | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | June 11, 2019 títí di ìsinsìnyí |
Asíwájú | Sen. Ahmed Abubakar Mo'Allahyidi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | January 1, 1955 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Bàbá | Dauda Yaroe |
Profession | Politician |
Wọ́n bí Binos Dauda Yaroe ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 1955, ní Wagole, abúlé kan ní agbègbè Ribadu Ward ti ìjọba ìbílè Mayo-Belwa ní Ìpínlẹ̀ Adámáwá, Nàìjíríà. Ó fẹ́ Mrs. Gimbiya Joshua, ní ọdún 1983; wọ́n bí ọmọ mẹ́rin.[5]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.