Benin
From Wikipedia, the free encyclopedia
Benin (pípè /bɨˈnɪn/) tàbí Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Benin jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Ìwọ̀orùn Áfríkà. Ó ní bodè pẹ̀lú Togo ní apá ìwọòrùn, Nàìjíríà ní apá ìlaòrùn, àti Burkina Faso àti Nijẹr ní àríwá. Ní gúúsù ó jásí Etíòkun Benin (Bight of Benin).
Quick Facts Republic of BeninOrílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Benin République du Bénin, Olùìlú ...
Republic of Benin Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Benin République du Bénin
| |
---|---|
Olùìlú | Porto-Novo1 |
Ìlú tótóbijùlọ | Cotonou |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Faransé |
Orúkọ aráàlú | Ara Benin; Omo ile Benin |
Ìjọba | Oselu egbe oloselu pupo |
• Aare | Patrice Talon |
Òmìnira kúrò lọ́wọ́ Fransi | |
• Ọjọ́ | August 1,1960 |
Ìtóbi | |
• Total | [convert: invalid number] (101st) |
Alábùgbé | |
• July 2005 estimate | 84390002 (89th) |
• 2009 census | 6769914 |
• Ìdìmọ́ra | 75/km2 (194.2/sq mi) (118th3) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $13.014 billion[1] (140th) |
• Per capita | $1,605[1] (166th) |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $6.940 billion[1] |
• Per capita | $856[1] |
Gini (2003) | 36.5 medium |
HDI (2007) | ▲ 0.437 Error: Invalid HDI value · 163rd |
Owóníná | West African CFA franc (XOF) |
Ibi àkókò | UTC+1 (WAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | 229 |
ISO 3166 code | BJ |
Internet TLD | .bj |
|
Close
Itobi re ko fi be ju 110000 km2 lo pelu arabudo to fe e to 8,500,000. Botileje pe oluilu re je Porto Novo ibujoko ijoba wa ni Kútọnu.
Leyin ijoba oloselu lati 1960 de 1972, ijoba Marxist-Leninist je lati 1972 titi de 1991, ijoba yi se inira pupo, o si se idabaru inadura. Bere lati odun 1991, awon idiboyan egbe oloselupupo ti n waye.