![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/6/63/Beatrice_Straight_%2528Patterns%2529.png/640px-Beatrice_Straight_%2528Patterns%2529.png&w=640&q=50)
Beatrice Straight
From Wikipedia, the free encyclopedia
Beatrice Whitney Straight (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹjọ ọdún 1914, tí ó sìn kú ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 2001), nígbà ayé rẹ̀ jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, àti gbajúmọ̀ nínú ẹbí Whitney ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ Academy Award, àmìn ẹ̀yẹ Tony àti adíje àmìn ẹ̀yẹ Emmy.[1]
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Beatrice Straight | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | Beatrice Whitney Straight (1914-08-02)Oṣù Kẹjọ 2, 1914 Old Westbury, New York, U.S. |
Aláìsí | April 7, 2001(2001-04-07) (ọmọ ọdún 86) Los Angeles, California, U.S. |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1939–1991 |
Olólùfẹ́ | Louis Dolivet (m. 1942; div. 1949) Peter Cookson (m. 1949; his death 1990) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Parent(s) | Willard Dickerman Straight Dorothy Payne Whitney |
Àwọn olùbátan | Whitney W. Straight Michael W. Straight |
Close