Afghanístàn
From Wikipedia, the free encyclopedia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Afghanístàn ( /æfˈɡænᵻstæn,_æfˈɡɑːnᵻstɑːn/; Pashto/Dari: افغانستان, Pashto: Afġānistān [avɣɒnisˈtɒn, ab-],[lower-alpha 1] Dari: Afġānestān Àdàkọ:IPA-fa), àlòṣiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn, ni is a orílẹ̀-èdè onílẹ̀bodè ní Gúúsù àti Àrin Ásíà. Afghanístàn ní bodè mọ́ Pakistan ní ìlà-òrùn àti ní gúúsù;[lower-alpha 2] mọ́ Iran ní ìwọ̀-òrùn; mọ́ Turkmenistan, Uzbekistan, àti Tajikistan ní àríwá; àti mọ́ Ṣáínà ní àríwá-ìlàòrùn. Gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀ fẹ̀ tó 652,000 square kilometers (252,000 sq mi), orílẹ̀-èdè olókè ní tó ní ilẹ̀ pẹpẹ ní apá àríwá àti gúúsù-ilàòrùn. Kabul ni olúìlú àti ilú tótóbijùlọ níbẹ̀. Iye aráàlú ibẹ̀ fẹ́ ẹ̀ pọ̀ tó 32 mílíọ́nù, tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà àwọn Pashtun, Tajik, Hazara àti Uzbek.
Islamic Republic of Afghanistan
| |
---|---|
Orin ìyìn: Millī Surūd ملي سرود ("National Anthem") | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Kabul 33°N 65°E |
Official languages | Dari 27 million (77%) (L1 + L2), Pashto 16.8 million (48%)[2] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | |
Ẹ̀sìn |
|
Orúkọ aráàlú | Afghan[Note 1][6][7] |
Ìjọba | Unitary presidential Islamic republic |
Ashraf Ghani | |
• 1st Vice President | Amrullah Saleh |
• 2nd Vice President | Sarwar Danish |
Aṣòfin | National Assembly |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | House of Elders |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | House of the People |
Formation | |
• Hotak Empire | 21 April 1709 |
• Durrani Empire | July 1747 |
• Emirate | 1823 |
• Recognized | 19 August 1919 |
• Kingdom | 9 June 1926 |
• Republic | 17 July 1973 |
• Current constitution | 26 January 2004 |
Ìtóbi | |
• Total | 652,230[8] km2 (251,830 sq mi) (40th) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• 2019 estimate | 32,225,560[9] (44th) |
• Ìdìmọ́ra | 46/km2 (119.1/sq mi) (174th) |
GDP (PPP) | 2018 estimate |
• Total | $72.911 billion[10] (96th) |
• Per capita | $2,024[10] (169th) |
GDP (nominal) | 2018 estimate |
• Total | $21.657 billion[10] (111st) |
• Per capita | $601[10] (177th) |
Gini (2008) | 27.8[11] low · 1st |
HDI (2018) | ▲ 0.496[12] low · 170th |
Owóníná | Afghani (Afs) (AFN) |
Ibi àkókò | UTC+4:30 Solar Calendar (D†) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +93 |
ISO 3166 code | AF |
Internet TLD | .af افغانستان. |
Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tí wọ́n sọ pé ó wà ní ìlú yìí lé díẹ̀ ní mílíònù mọ́kànlélógún (21,017.000). Èdè tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí tó àádọ́ta ṣùgbọ́n ìlàjì nínú àwọn tí ó wà ní ìlú náà ni ó ń sọ páṣítọ̀ (Pashto) tí òun àti Dárì jọ jẹ èdè ìjọba (official language). Dárì (Dari) yìí nì orúkọ tí wọ́n ń pe Persian (Pásíà) ní Afuganísítàànù. Dárí yìí ṣe pàtàkì gan-an ni gẹ́gẹ́ bí èdè tí ìjọba ń lò (lingua franca). Fún ti òwò tí ó jẹ mọ gbogbo àgbáyé, èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí ni Tadzhik, Uzbek, Turkmen, baluchi, Brachic àti pashayi
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.