Allah

From Wikipedia, the free encyclopedia

Allah

Allah (Lárúbáwá: الله Allāh, IPA: [ʔalˤːɑːh]  ( listen)) ni oro fun Olorun ni ede Arabiki.[1] Botilejepe a mo nibo miran bi oro awon musulumu fun Olorun, oro yi gbogbo na ni awon Arabu yioku onigbagbo Abrahamu unlo fun "Olorun", awon bi Mizrahi Jews, Baha'is ati Eastern Orthodox Christians.[1][2][3] Oro yi na tun ni awon keferi ara Meka na tu lo fun olorun-eleda, o seese ko je orisa igba na ni Arabia akosiwaju-Imale.[4][5]


Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.