![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/c/c9/Ado_at_Minna_Book_Fair.jpg/640px-Ado_at_Minna_Book_Fair.jpg&w=640&q=50)
Ado Ahmad Gidan Dabino
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ado Ahmad Gidan Dabino, jẹ́ òǹkọ̀wé èdè Hausa,[1] òǹkọ̀wé, akéde, oníròyìn, olùṣe fíìmù, olùdarí àti òṣèré fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó kọ̀wé fún bíi ọgbọ̀n ọdún lórí àwọn àkọ́lé oríṣiríṣi. Ó ti ṣàgbéjáde àwọn ìwé ìtàn àròsọ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún. Ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ Member of the Order of the Niger (MON) ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án, ọdún 2014, láti ọwọ́ Ààrẹ Goodluck Ebele Jonathan.[2][3]
Quick Facts Ọjọ́ ìbí, Iṣẹ́ ...
Ado Ahmad Gidan Dabino | |
---|---|
![]() Gidan Dabino MON | |
Ọjọ́ ìbí | 1 Oṣù Kínní 1964 (1964-01-01) (ọmọ ọdún 60) |
Iṣẹ́ |
|
Èdè | Hausa |
Website | |
gidandabino.com.ng |
Close