Air pollution in Delhi
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Use Indian English
Dídara afẹ́fẹ́ ni Delhi ní orílé èdè Índíà, gẹ́gẹ́ bí Ìwádìí láti ọwọ́ Àjọ Àgbáyé fún Ìlera |WHO] ti gbé àwọn ìlú lọ́na 1,650 yẹ́wó àti ṣe ìwádìí lórí awọn ilu ní agbaye lọnà 7,000 láti ọwọ́ Ilé-iṣẹ́ tí ó má nipa Ìlera ní orílé èdè America [2] ni ó burú jù ní eyíkéyí ilu ní àgbáyé. Ó tún kan àwọn agbègbè kan ní àyíká Delhi.[3][4] Ìdọ̀tí inú Afẹ́fẹ́ ní Íńdíà ní àfojú díwọ̀n iyé máa ń pa nǹkan bí mílíọ̀nù méjì ènìyàn lọ́dọọdún; Ó jẹ́ ààrùn apànìyàn kàrún tí ó tóbi jùlọ ní India. Orílè-èdè India ní òṣùwọn ikú tí ó ga jùlọ ní àgbáyé èyí tí àwọn àrùn atẹ́gùn, àwọn àrùn ikọ́ ife ati ààrùn inú eegun wá lára àwọn ààrùn, Gẹ́gẹ́ bí àjọ WHO náà tisọ. Ni Delhi, afẹ́fẹ́ tí kò dára tí ó jẹ́ pé bí ó báti wọ inú àgọ̀ ará máa ǹ bá nǹkan jẹ́ nínú ará èyí tí kòsí ní àtúnṣe máa ń bá ẹ̀dọ̀fóró jẹ́ tí bá to mílílọ̀nù méjì ẹdọfóró jẹ́, èyí tí ìlàjì sí jẹ́ àwọn ọmọdé.
Ní ọjọ́ 25 Oṣù kọkànlá ọdún 2019, Ilé Ẹjọ́ gíga tí ilé India ṣé àwọn àlàyé lórí ìdọ̀tí ní Delhi nínú ọ̀rọ̀ sisọ rẹ̀ “Delhi ti buru ju Naraka lọ (ọ̀run apáàdì lọ)".[5] Adájọ àgbà Justice Arun Kumar Mishra pé ì bá dáa tí wọ́n bá rí àwọn olóró èyí tí yóò yàrá pani jù ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ lọ[6]
Lákòkò ìtìpa àgbáyé látàrí Àjàkáyẹ́ ààrùn COVID-19 èyí tí kò yọ Orílẹ̀-èdè India sílẹ, Omi tí àwọn odò Yamuna àti Ganges tí dára èyí sì tí mú ìlọsíwájú bá àwọn ilé-iṣẹ́ tí wá ní agbègbè ibẹ̀ látàrí títìpa ílú nítorí àjàkálẹ̀ ààrùn COVID-19.[7][8][9][10] Dídára afẹ́fẹ́ tún ti ní ìlọsíwájú pàtàkì ní àkókò títìpa.[11]Ní Orílẹ-èdè India ilé-iṣẹ́ ti ó mójútó Àwọn sáyẹ́nsì Àyè tí ṣe àtẹ̀jáde ìwé ìwádìí kan ní Oṣù Kẹwà ọdún 2018 tí ó sọ pé ó fẹ́rẹ̀ tó 41% sí àwọn ìtújàdè èefín ọkọ̀, 21.5% sí jẹ́ eruku nígbà tí 18% sì awọn ile-iṣẹ.[12] Olùdarí ilé iṣé fún ìmọ sáyẹnsì àti agbègbè tí fi ẹsùn kàn pé ilé iṣé Automotive ní orílé èdè India àti àwọn ọmọ ẹgbẹ Indian Automobile Manufacturers ń parowa “tí ó lòdì sí ìjábọ̀ náà” nítorí pé kò “rọrùn” sí ilé-iṣẹ́ tí ó ń ṣe Ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́[13]