![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b1/WLA_hmns_Garnet_and_Diamond_necklace_2.jpg/640px-WLA_hmns_Garnet_and_Diamond_necklace_2.jpg&w=640&q=50)
Ẹ̀gbà Ọrùn
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ẹ̀gbà Ọrùn jẹ́ ohun tí àwọn ènìyàn ọkùnrin àti obìnrin lń lòbláti fi ṣe ọ̀ṣọ́ ara. [1] Àwọn ènìyàn sábà ma ń lòó níbi àwọn ayẹyẹ bíb: ayẹyẹ, ẹ̀sìn, or ìsìnkú, ìkómọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ó tún wà fún ṣíse àdáyanrí tàbí ìyàtọ̀ láàrín olówó àti tálíkà láàrín àwùjọ. Ọ̀pọ̀ nínú àwọn ẹ̀gbà ọrùn wọ̀nyí ni wọ́n fi ohun èlò oníyebíye ṣe. Papòọ̀ nínú àwọn ẹ̀gbà ọrùn yí ni wọ́n ma ń ṣe pẹ̀lú ìlẹ̀kẹ̀ yálà iyùn sẹ̀gi, tàbí àko àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ẹ̀gbà ọrùn míràn ni wọ́n di góólù, ìdẹ, bàbà àti àwọn òkúta oníyebíye mìíràn ṣe. [2]
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b1/WLA_hmns_Garnet_and_Diamond_necklace_2.jpg/640px-WLA_hmns_Garnet_and_Diamond_necklace_2.jpg)