Ẹurásíà
orílẹ̀ / From Wikipedia, the free encyclopedia
Ẹurásíà je isupoile nla to je bi 52,990,000 km2 (20,846,000 mi2) tabi bi 10.6% ojude Aye (36.2% agbegbe ile). Nigba miran o je gbigba gege bi orile kan soso,[1] Eurasia je apapo awon orile Europe and Ásíà (Eurasia jade ninu oruko won), eyi wa latojo pipe.
Eurasia je ibugbe fun 4.8 legbegberunkeji eniyan, iye to ju 71% onibugbe aye lo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |