Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Willard Carroll "Will" Smith Jr. (ojoibi September 25, 1968)[2] je osere, olootu, rapper, alawada ati ako-orin ara Amerika. Ni osu April 2007, Newsweek pe ni "osere to lagbarajulo ni Hollywood".[3] Smith ti je yiyan fun Ebun Golden Globe marun ati Ebun Akademi meji, be sini o ti gba Ebun Grammy merin.
Will Smith | |
---|---|
Smith at the 2017 San Diego Comic-Con International | |
Ọjọ́ìbí | Willard Carroll Smith Jr. 25 Oṣù Kẹ̀sán 1968 Philadelphia, Pennsylvania, U.S. |
Ibùgbé | Los Angeles, California, U.S. |
Orúkọ míràn | The Fresh Prince |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1985–present |
Net worth | Àdàkọ:Gain $250 million (2014)[1] |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | Trey, Jaden, and Willow Smith |
Musical career | |
Irú orin | Hip hop |
Labels |
|
Associated acts |
|
Website | willsmith.com |
Signature | |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.