From Wikipedia, the free encyclopedia
Paul Robin Krugman (pípè /ˈkruːɡmən/;[3] ojoibi February 28, 1953) je onimo ikowo, alayokakiko ati olukowe omo orile-ede Amerika. O je Ojogbon Oro Okowo ati Ikariaye ni Woodrow Wilson School of Public and International Affairs, Yunifasity Princeton, Ojogbon Centenary ni London School of Economics, ati akoro olootu fun The New York Times.[4][5] Ni 2008, Krugman gba Ebun Iseranti Nobel ninu Oro-okowo fun afikun re si Ero Idunaduna Tuntun ati Jeografi Oro-Okowo Tuntun. Iwe-iroyin igbadegba Prospect Magazine diboyan gege bi omowe eni ekefa larin awon 100 tolewaju lagbaye ni 2005.[6]
New Keynesian economics | |
---|---|
Paul Krugman (2008) | |
Nationality | American |
Institution | Princeton University |
Field | International economics, Macroeconomics |
Alma mater | MIT (Ph.D.) Yale University (B.A.) |
Opposed | Freshwater economics[1][2] |
Influences | John Maynard Keynes Jagdish Bhagwati Rudi Dornbusch James Tobin Avinash Dixit Joseph Stiglitz |
Influenced | Marc Melitz |
Contributions | International Trade Theory New Trade Theory New Economic Geography |
Awards | John Bates Clark Medal (1991) Nobel Memorial Prize in Economics (2008) |
Information at IDEAS/RePEc |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.