From Wikipedia, the free encyclopedia
Nepal (Nepali: नेपाल Àdàkọ:IPA-ne), àlòṣiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nepal,[12] jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní Gúúsù Ásíà. Gbogbo rẹ̀ búdòó sí àwọn òkè Himalayas, sùgbọ́n ó tún ní àwọn apá Indo-Gangetic Plain. Nepal ni orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ 49k gẹ́gẹ́bí iye èniyàn àti orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ 93k gẹ́gẹ́bí agbègbè. Nepal jẹ́ orílẹ̀-èdè àrin-ilẹ̀, ó sì ní bodè mọ́ Ṣáínà ní àríwá àti mọ́ Índíà ní gúúsù, ìlàòrùn àti ìwọ̀òrùn, nígbàtí Bangladesh wà ní 27 km (17 mi) sí etí apágúúsùilàòrùn àti Bhutan jìnnà si látọ̀dò ìpúnlẹ̀ India Sikkim. Nepal has a diverse geography, including fertile plains, subalpine forested hills, and eight of the world's ten tallest mountains, including Mount Everest, the highest point on Earth. Kathmandu is the capital and the largest city. Nepal is a multiethnic country with Nepali as the official language.
Federal Democratic Republic of Nepal
| |
---|---|
Motto: "Janani Janmabhumishcha Swargadapi Gariyasi" (Sanskrit) "Mother and motherland are greater than heaven" | |
Orin ìyìn: "Sayaun Thunga Phulka" "Made of Hundreds of Flowers" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Kathmandu 28°10′N 84°15′E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Nepali |
Lílò national languages | All mother-tongues[1][2] (see Languages of Nepal) |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2011) | Àdàkọ:Ublist |
Ẹ̀sìn | Àdàkọ:Ublist |
Orúkọ aráàlú | Nepali, Nepalese |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira oníléaṣòfin ìjọba àpapọ̀ |
• Ààrẹ | Bidhya Devi Bhandari (विद्यादेवी भण्डारी)[3] |
• Igbakeji Aare | Nanda Bahadur Pun (नन्दबहादुर पुन) |
• Alákóso Àgbà | Sher Bahadur Deuba (शेरबहादुर देउवा) |
• Agbẹnusọ Ilé-aṣojú | Agni Prasad Sapkota (अग्नि प्रसाद सापकोtटा)[4] |
• Olùdájọ́ Àgbà | Cholendra Shumsher JB Rana (चोलेन्द्र शम्शेर ज.ब.रा.)[5] |
Aṣòfin | Ilé-aṣòfin Ìjọ́ba Àpapọ̀ |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | Ilé àwọn Aṣojú |
Formation | |
• Ilẹ̀ọba | 1768[6] |
• Federal Republic | 28 May 2008 |
• Current constitution | 20 September 2015 |
Ìtóbi | |
• Total | 147,516 km2 (56,956 sq mi) (93rd) |
• Omi (%) | 2.8 |
Alábùgbé | |
• Àdàkọ:UN Population estimate | ▲ Àdàkọ:UN PopulationÀdàkọ:UN Population (49th) |
• 2011 census | 26,494,504[7] |
• Ìdìmọ́ra | 180/km2 (466.2/sq mi) (50th) |
GDP (PPP) | 2019 estimate |
• Total | ▲ $94 billion[8] (87th) |
• Per capita | ▲ $3,318[8] (155th) |
GDP (nominal) | 2019 estimate |
• Total | ▲ $30 billion (101st) |
• Per capita | ▲ $1,048[8] (159th) |
Gini (2010) | 32.8[9] medium · 115th |
HDI (2019) | ▲ 0.579[10] medium · 147th |
Owóníná | Nepalese rupee (Rs, रू) (NPR) |
Ibi àkókò | UTC+05:45 (Nepal Standard Time) |
DST not observed | |
Mains electricity | 230 V–50 Hz[11] |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +977 |
ISO 3166 code | NP |
Internet TLD | .np |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.