Nandi Nyembe
òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Nandi Nyembe (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1950)[1] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Zone 14 àti Soul City.
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹpẹ ayé re
Wọ́n bíi Nyembe sì ìlú Kliptown ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà ni ọdún 1950, ó sì ti gbé ní àwọn ìlú bíi Botswana, East London àti South Áfríkà nígbà ti o si kéré[2][3]. Nyembe sọ wí pé wọn má fi òhun ṣe ọmọ ọ̀dọ̀ nínú eré nítorí pé ohun jẹ́ ọmọ ilẹ̀ adúláwò.[4]
Iṣẹ́
Nyembe gbajúmọ̀ fún ipá Nandi Sabiya tí ó kó nínú eré Zone 14. Ó ṣe Lily nínú eré Yizo Yizo (2001-2004). Ó ti kopa ninu awọn eré bíi Reasonable Man (1999), Saturday Night at the Palace (1987) ati Yesterday (2004)[5][6]. Ní ọdún 2007, ó farahàn gẹ́gẹ́ bí Thembe Makhubu nínú dírámà tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Jacob's Cross. Àwọn dírámà tí ó tún kopa ninu wọn níí Sticks and Stones, Ashes to Ashes.[7][8]
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí se
Eré orí tẹlẹfísọ̀nù
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads