Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Medgar Wiley Evers (July 2, 1925 – June 12, 1963) je omo Afrika Amerika alakitiyan awon eto araalu lati Mississippi to kopa lati fopin si to eleyameya ni University of Mississippi. O di alakitiyan ninu egbe irinkankan fun awon eto araalu leyin igba to pada de ati ise oke okun ninu Ogun Agbaye 2k to si pari eko agba; o di akowe ori papa fun NAACP. O wo ise ologun ni odun 1943. Won yinbon fun un ni deede agogo kan ku ogun isegun loru ojo kejila, odun 1963 ni oju ona ile re jackson, Missisippi.
Medgar Wiley Evers | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Decatur, Mississippi U.S. | Oṣù Keje 2, 1925
Aláìsí | June 12, 1963 ọdún 37) Jackson, Mississippi, U.S. | (ọmọ
Iṣẹ́ | Civil rights activist |
Olólùfẹ́ | Myrlie Evers-Williams 1951–1963 (his death) |
Àwọn ọmọ | Meta |
Parent(s) | James Evers (father)[1] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.