Mary Uranta

Akọrin obìnrin From Wikipedia, the free encyclopedia

Mary Uranta
Remove ads

Mary Data Uranta jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Wọn bíi sí ìlú Portharcourt, ibè sì ni ó gbé dàgbà. Ó wá lára àwọn tó díje fún ipò obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni ilẹ̀ Niger Delta, ó sì gbé ipò kejì. Uranta bẹ̀rẹ̀ ère ṣíṣe ni ọdún 2000 pelu eré Girls Hostel. Ní ọdún 2006, ó di gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Secret Mission. Ó dà egbe Mary Uranta Foundation kalẹ láti pèsè iranlọwọ fún àwọn ọmọdé ni ìlú Opobo. Ó ti gba ebun lati ọdọ City People Awards àti African Youth Ambassador Award.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

Uranta dàgbà ni ìlú Portharcourt ni ìpínlè Rivers.[1] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Holy Rosary Girls Secondary school kí ó tó tesiwaju sì ilẹ̀ ẹ̀kọ́ gíga tí Rivers State University of Science and Technology níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Secretarial Administration.[2]

Awọn Itọkasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads