From Wikipedia, the free encyclopedia
Kòréà Gúúsù, fun onibise gege bi Orile-ede Olominira ile Korea (ROK) (Àdàkọ:Lang-ko, pípè [tɛːhanminɡuk̚] ( listen)), je orile-ede ni Ilaorun Asia, to budo si ilaji apaguusu Korean Peninsula. O ni bode mo Saina ni iwoorun, Japan ni ilaorun, ati Ariwa Korea ni ariwa. Oluilu re ni Seoul. Guusu Korea dubule si agbegbe ojuojo lilowooro pelu awon oke. Agbegbe bo itobi to je 100,032 ilopo awon kilomita mole, o si ni iye eniyan to ju egbegberun 50 lo.[5]
Republic of Korea [대한민국] error: {{lang}}: unrecognized script: lang for code: ko (help) 大韓民國 Daehanmin(-)guk | |
---|---|
Motto: Benefit all mankind (홍익인간) (Unofficial motto) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Seoul |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Korean |
Official scripts | Hangul |
Orúkọ aráàlú | South Korean, Korean |
Ìjọba | Presidential republic |
• President | Moon Jae-in (문재인 , 文在寅) |
• Prime Minister | Kim Boo-kyum (김부겸 , 金富謙) |
Aṣòfin | National Assembly |
Establishment | |
Ìtóbi | |
• Total | 100,210 km2 (38,690 sq mi) (108th) |
• Omi (%) | 0.3 |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 48,875,000[1] (24th) |
• Ìdìmọ́ra | 491/km2 (1,271.7/sq mi) (21st) |
GDP (PPP) | 2010 estimate |
• Total | $1.457 trillion[2] |
• Per capita | $29,790[2] |
GDP (nominal) | 2010 estimate |
• Total | $986.256 billion[2] |
• Per capita | $20,165[2] |
Gini (2007) | 31.3[3] Error: Invalid Gini value |
HDI (2010) | ▲ 0.877[4] Error: Invalid HDI value · 12th |
Owóníná | South Korean won (₩) (KRW) |
Ibi àkókò | UTC+9 (Korea Standard Time) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+9 (not observed) |
Irú ọjọ́ọdún | yyyy년 mm월 dd일 yyyy/mm/dd (CE) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 82 |
ISO 3166 code | KR |
Internet TLD | .kr |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.