Kim Basinger

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Kim Basinger
Remove ads

Kim Basinger je osere to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iléẹ̀kọ́ gíga ...
Remove ads

Ìgbèsi Àyè Áràbinrin naa

Basinger ni a bini Athens, Georgia ni Ọdun 1953 fun An Lee (1925-2017) ati Donald Wade (1923-2016). Basinger jẹ alumna ti William Esper Studio fun performing arts ni Manhattan, New York City[2]. Ki Óṣèrè lóbinrin naa to gbàjumọ ni ó fẹ Tim Saunders, Dale Robinette ati Joe Namath. Ni Óṣù October, ọdun 1980, Kim fẹ Ron Synder-Britton ti wọn si pinya ni ọdun 1989.

Ni ọdun 1990, Kim pade ọkọ rẹ keji Alec Baldwin ti wọn si fẹ ara wọn ni óṣu August ni ọdun 1993 ti wọn si bi ọmọ óbinrin Ireland Eliesse Baldwin ti wọn bi ni Óṣu October, ọdun 1995[3]. Tọkọ Taya naa pinya ni ọdun 2002. Ni ọdun 2014, Kim fẹ Mitch Stone ti wọn si bẹrẹ si ni gbè pọ lati igba naa[4].

Remove ads

Ẹkọ

Basinger kẹkọ nipa Ballet lati ọmọ ọdun mẹta. Óṣèrè lóbinrin naa kẹkọ ni ilè iwè giga Georgia[5].

Àmi Ẹyẹ ati Idànilọlà

Kim gbà ami ẹyẹ ti Akademi, Àmi ẹyẹ ti Golden Globe, Àmi ẹyẹ ti Óṣèrè Screen Guils ati irawọ ti Hollywood Walk of Fame[6].

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads