Josephine Baker

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Josephine Baker
Remove ads

Josephine Baker (June 3, 1906 – April 12, 1975) je onijo, akorin ati osere omo Amerika ara Fransi to je mimo kaakiri bi "Black Pearl," "Bronze Venus" ati "Creole Goddess". Oruko abiso re ni Freda Josephine McDonald ni St. Louis, Missouri, Josephine di ara Fransi ni 1937. O gbo ede Geesi ati ede Fransi daada.

Quick Facts Background information, Orúkọ àbísọ ...

Baker ni omobinrin Afrika Amerika akoko to di osere pataki ninu filmu kan, Zouzou (1934) tabi to gbajumo kari aye gegebi onifaaji. Baker ko lati sere fun agbo eleyameya ni Amerika, be sini o tun kopa ninu Iwode awon Eto Araalu. Coretta Scott King fun ni ipo olori iwode yi ni odun 1968, leyin ifikupa Martin Luther King, Jr.. Baker, however, turned down the offer. She was also known for assisting the French Resistance during World War II,[3] and received the French military honor, the Croix de guerre and was made a Chevalier of the Légion d'honneur by General Charles de Gaulle.[4]

Remove ads

Ìgbésíayé

Wọ́n bí Josephine Baker pẹ̀lú orúkọ àbísọ Freda Josephine McDonald ní St. Louis, Missouri, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.[1][2] Ìyá rẹ̀ ni Carrie McDonald. Bàbá rẹ̀ ni Eddie Carson tó jẹ́ onílù. Carrie àti Eddie dá ẹgbẹ́ orin àti ijó sílẹ̀, had a song-and-dance act, playing wherever they could get work, and when Josephine was about a year old they began to carry her onstage occasionally during their finale. Josephine was always poorly dressed and hungry, and her playground became the yards of Union Station. From this she developed her street smarts.[5] When Baker was eight she began working as a live-in domestic for white families in St. Louis.[6] She was sent to work for a woman who abused her, burning Baker's hands when she put too much soap in the laundry.[7]


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads