Jennifer Beals
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Jennifer Beals (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejìlá, ọdún 1963)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin ará Amerika àti àwòkọ́ṣe ọ̀dọ́mọkùnrin télẹ̀. Ó ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ nínú My Bodyguards ní ọdún 1980, kí ó tó gba ìyin pàtàkì fún ipa rẹ̀ nínú Flashdance ní ọdún 1983, èyí sì mu gba àmì-ẹ̀yẹ NAACP fún òṣèré tíátà tó tayọ jù lọ, wọ́n tún yàn án fún àmì-èyẹ Golden Globe.

Beals ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olókìkí bíi Devils in a Blue Dress ní ọdún 1995, The Last Days of Disco ní ọdún 1988, Roger Dodger ní ọdún 2002, The Book of Eli ní ọdún 2010, àti Before I Fall ní ọdún 2017. Lórí tẹlifíṣọ́ọ̀nù, ó ṣe ẹ̀dá-ìtàn Bette Porter nínú The L Word, ní ọdún 2004 sí ọdún 2009. Lẹ́yìn náà, ó farahàn gẹ́gẹ́ bíi ẹ̀dá-ìtàn kan pàtàkì nínú The Chicago Code ní ọdún 2011, Proof ní ọdún 2015, Taken ní ọdún 2017, àti The Book of Boba Fett ní ọdún 2021. Ó tẹ̀síwájú nínú ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù The L Word: Generation Q gẹ́gẹ́ bíi Bette Porter ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ oṣù kejìlá, ọdún 2019.
Remove ads
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
Fíìmù
Orí tẹlifíṣọ́ọ̀nù
Gẹ́gẹ́ bíi aṣàgbéjáde fíìmù
Remove ads
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ tí ó gbà
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
