Goldie Hawn
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Goldie Hawn je óṣèrè lóbinrin ti ilẹ america to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[2].
Goldie Hawn | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | Goldie Jeanne Hawn 21 Oṣù Kọkànlá 1945[1] Washington, D.C., U.S. |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1966–present |
Olólùfẹ́ |
|
Alábàálòpọ̀ | Kurt Russell (1983–present) |
Àwọn ọmọ |
|
Ìgbèsi Àyé Àrabinrin naa
Hawn ni à bini Washington, D.C. fun Laura ati Edward Rutledge Hawn[3]. Óṣèrè lóbinrin naa ni à sọ orukọ rẹ latara aunt iya rẹ. Baba Goldie ni Presbyterian ti German ti iran rẹ sijẹ ti èdè gẹẹsi ṣùgbọn iya rẹ wa lati iran jew[4][5]. Hawn ni a tọ ni ilana jew ni Takoma Park, Maryland. Hawn bẹrẹ sini kọ ballet ni igba to pè ọmọ ọdun meta to si jó ni Corps de ballet ti Ballets Russes de Monte Carlo production ti Nutcracker ni ọdun 1955.
Ki Hawn to gbajumọ ni ó fẹ óṣèrè lọkunrin Mark Goddard ati ólórin Spiro Venduras Ọkọ akọkọ ti óṣèrè lóbinrin naa ni Gus Trikonis ti wọn si fẹ ara wọn ni óṣu may ọdin 1969. Tọkọ Taya naa pinya ni óṣu April ni ọdun 1973[6].
Hawn fẹ Bill Hudson ni óṣu July ọdun 1976 ti wọn si bi ọmọ meji; ọmọ ókunrin Oliver (Óṣu September, ọdun 1976) ati ọmọ óbinrin Kate (Óṣu April ọdun 1980)[7]. Tọkọ Taya naa pinya ni Óṣu march ọdun 1982[8]. Hawn bẹrẹ sini wọlè wọde pẹlu Óṣèrè lọkunrin Kurt Russell ni ọdun 1983 ti wọn si bi ọmọ ọkunrin Wyatt ni óṣu july ọdun 1986[9].
Ẹkọ
Hawn kẹkọ ni ilè iwè Montgomery Blair ni Silver Spring, Maryland. Óṣèrè lóbinrin naa lọsi ilè iwè giga ti America nibi ti ó ti kẹkọ drama ṣugbọn ko ka iwé rẹ tan to fi lọ ṣè ólukọ ni ilè iwè ballet[10].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
Association | Ọdun | Category | Iṣẹ | Èsi | Ref(s) |
---|---|---|---|---|---|
Academy Awards | 42nd Academy Awards|1970 | Best Supporting Actress | Cactus Flower | Gbàá | [11] |
53rd Academy Awards|1981] | Best Actress | Private Benjamin | Wọ́n pèé | [12] | |
American Comedy Awards | 1987 | Funniest Actress in a Motion Picture (Leading Role) | Wildcats | Wọ́n pèé | [13] |
1988 | Overboard | Wọ́n pèé | [14] | ||
1993 | Housesitter | Wọ́n pèé | |||
1997 | The First Wives Club | Wọ́n pèé | [15] | ||
Bambi Awards | 1999 | International Film Actress | N/A | Gbàá | |
British Academy Film Awards | 24th British Academy Film Awards|1971 | Best Actress in a Leading Role | Cactus Flower There's a Girl in My Soup |
Wọ́n pèé | [16] |
National Association of Theatre Owners#CinemaCon|CinemaCon Awards | 2017 | Cinema Icon Award | N/A | Gbàá | [17] |
David di Donatello|David di Donatello Awards | 1970 | Special David Award | Cactus Flower | Gbàá | [18] |
Goldene Kamera|Goldene Kamera Awards | 2005 | Lifetime Achievement Award | N/A | Gbàá | [19] |
Golden Globe Awards | 27th Golden Globe Awards|1970 | Best Supporting Actress – Motion Picture | Cactus Flower (film)|Cactus Flower | Gbàá | [20] |
New Star of the Year – Actress | Wọ́n pèé | ||||
30th Golden Globe Awards|1973 | Golden Globe Award for Best Actress – Motion Picture Comedy or Musical|Best Actress – Motion Picture Comedy or Musical | Butterflies Are Free | Wọ́n pèé | ||
33rd Golden Globe Awards|1976 | Shampoo | Wọ́n pèé | |||
34th Golden Globe Awards|1977 | The Duchess and the Dirtwater Fox | Wọ́n pèé | |||
36th Golden Globe Awards|1979 | Foul Play | Wọ́n pèé | |||
38th Golden Globe Awards|1981 | Private Benjamin | Wọ́n pèé | |||
40th Golden Globe Awards|1983 | Best Friends | Wọ́n pèé | |||
60th Golden Globe Awards|2003 | The Banger Sisters | Wọ́n pèé | |||
Golden Raspberry Awards | 22nd Golden Raspberry Awards|2002 | Golden Raspberry Award for Worst Supporting Actress|Worst Supporting Actress | Town & Country | Wọ́n pèé | [21] |
38th Golden Raspberry Awards|2018 | Snatched | Wọ́n pèé | [22] | ||
Hasty Pudding Theatricals | 1999 | Hasty Pudding Woman of the Year | N/A | Gbàá | [23] |
Hollywood Film Awards | 2003 | Outstanding Achievement in Acting | Gbàá | [24] | |
Hollywood Walk of Fame | 2017 | 2,609th Star – Motion Picture | Gbàá | [25] | |
National Board of Review|National Board of Review Awards | National Board of Review Awards 1996|1997 | Best Acting by an Ensemble (shared with the cast) | The First Wives Club | Gbàá | |
National Society of Film Critics|National Society of Film Critics Awards | 1980 National Society of Film Critics Awards|1981 | Best Actress | Private Benjamin (1980 film)|Private Benjamin | Wọ́n pèé | [26] |
New York Film Critics Circle|New York Film Critics Circle Awards | 1980 New York Film Critics Circle Awards|1981 | Best Actress | Runner-up | ||
People's Choice Awards | 7th People's Choice Awards|1981 | Favorite Motion Picture Actress (tied with Jane Fonda) | N/A | Gbàá | |
Primetime Emmy Awards | 21st Primetime Emmy Awards|1969 | Special Classification – Individuals | Rowan & Martin's Laugh-In | Wọ́n pèé | [27] |
32nd Primetime Emmy Awards|1980 | Outstanding Variety or Music Program | Goldie and Liza Together | Wọ́n pèé | [28] | |
Rembrandt Awards | 2008 | Honorary Award | N/A | Gbàá | [29] |
Satellite Awards | 1st Golden Satellite Awards|1997 | Best Supporting Actress – Comedy or Musical | Everyone Says I Love You | Wọ́n pèé | |
The Comedy Festival|US Comedy Arts Festival | 2006 | AFI Star Award | N/A | Gbàá | [30] |
Women in Film Crystal + Lucy Awards|Women in Film Crystal Awards | 1997 | Crystal Award | Gbàá | [31] |
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.