From Wikipedia, the free encyclopedia
Gilbert Fossoun Houngbo (ojoibi 4 February 1961[1]) je oloselu omo ile Togo to ti je Alakoso Agba ile Togo lati 8 September 2008.[2]
Gilbert Fossoun Houngbo | |
---|---|
Prime Minister of Togo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 8 September 2008 | |
Ààrẹ | Faure Gnassingbé |
Asíwájú | Komlan Mally |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 4 February 1961 |
Alma mater | University of Lomé |
Houngbo gba iwe eri giga ninu ibojuto isowo lati University of Lomé ni Togo, bakanna o tun gba iwe eri ninu isesiro ati inawo lati Université du Québec à Trois-Rivières ni Kanada. O je omo egbe Canadian Institute of Chartered Accountants.[3]
Ni Oṣu Kini Ọdun 2022, Gilbert Houngbo jẹ Alaga tuntun ti Igbimọ Alakoso Ohun elo Adayeba (NRGI).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.