Ìpínlẹ̀ Delta

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Ìpínlẹ̀ Delta

Ipinle Delta jẹ́ ọ̀kanIlára àwọn Ìpínlẹ̀ nií riílẹ̀-èdèNaijiria. Ìpínlẹ̀ Delta wà ní apá Gúúsù Nàìjíríà. Adá Ìpínlẹ̀ ìíkalẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù keẹjọ ọdún 1991lábé ìjọba Gen. Ibrahim Babangida [1]. Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Delta ni Asaba, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìlú Warri ni àárín ajé Ìpínlẹ̀ Delta. Àwọn èyà tí ópọ̀ jùlọ í Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri [2]. Ìpinlè Delta ní Ìjọba Àgbègbè Ìbílè márùndílọ́gbọ̀n (25) [3] Gómìnà Ifeanyi Okowa ní gómìnà Ìpínlẹ̀ Delta lọ́wọ́.

More information Location, Statistics ...
Ìpínlẹ̀ Delta
State nickname: The Big Heart
Location
Thumb
Statistics
Governor
(List)
Emmanuel Uduaghan (PDP)
Date Created 27 August 1991
Capital Asaba
Area 17,698 km²
Ranked 23rd
Population
1991 Census
2005 estimate
Ranked 9th
2,570,181
4,710,214
ISO 3166-2 NG-DE
Close

Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta

  • Ariwa Aniocha
  • Guusu Aniocha
  • Bomadi
  • Burutu
  • Guusu Ethiope
  • Ila-oorun Ethiope
  • Ariwa Ila-oorun Ika
  • Guusu Ika
  • Ariwa Isoko
  • Guusu Isoko
  • Ila-oorun Ndokwa
  • ìwọ̀ oòrùn Ndokwa
  • Okpe
  • Ariwa Oshimili
  • Guusu Oshimili
  • Patani
  • Sapele
  • Udu
  • Ariwa Ughelli
  • Guusu Ughelli
  • Ukwuani
  • Uvwie
  • Ariwa Warri
  • Guusu Warri
  • Guusu ìwọ̀ oòrùn Warri

Àwọn olókìkí ènìyàn láti Delta

  • Kefee, olori obinrin ati ko-orin Naijiria
  • Sunny Ofehe, olóṣèlú àti ajàfún òmìnira
  • Isaiah Ogedegbe, kọrinaọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.