Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Alhaji Olóyè Dauda Soroye Adegbenro (1909 - 1975) jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Naijiria to jẹ mínísítà fún ọrọ ilẹ pẹlu iṣẹ atí adari orilẹ-ède ti ẹgbẹ Action Group (AG).[1]
Ọdún 1909 ni wọ́n bí Adegbenro ní Ago-Owu, Abéòkúta, ìpínlẹ̀ Ògùn.[2] Dauda Soroye Adegbenro lọ sí ileewe African School, Owowo fún ètò ẹkọ alakọbẹrẹ ko to lọ sí Baptist Boys High School, Abéòkúta àti Abeokuta Grammar School fún ẹkọ gírámà.
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú àjọ Nigeria Railway Corporation gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé láti ọdún 1930 sí 1937. Lẹ́yìn ìyẹn, ó ṣiṣẹ́ olùtọ́jú ilé ìtajà pẹ̀lú United African Company.[3]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.