From Wikipedia, the free encyclopedia
Saint Martin (Faransé: Saint-Martin), lonibise bi Ikolejo ile Saint Martin (French: Collectivité de Saint-Martin) je ikolejo okere ti France to budo si Kàríbẹ́ánì. O wa saye ni 15 July 2007[3], o si ni awon apaariwa erekusu Saint Martin ati awon erekusu kekere itosi re, ninu won ti eyi totobiju je Île Tintamarre.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Collectivity of Saint Martin Collectivité de Saint-Martin
| |
---|---|
Orin ìyìn: La Marseillaise | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Marigot |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Mulatto, West African, Mestizo (French-East Asia), European, East Indian[1] |
Ìjọba | |
• President of France | Nicolas Sarkozy |
• Prefect | Dominique Lacroix |
• President of the Territorial Council | Frantz Gumbs |
Overseas collectivity of France | |
• Island divided between France and the Netherlands | 23 March 1648 |
• as separate Collectivity | 15 July 2007 |
Ìtóbi | |
• Total | 53.2 km2 (20.5 sq mi) (not ranked) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• Jan. 1, 2007 census | 35,925[2] |
• Ìdìmọ́ra | 675/km2 (1,748.2/sq mi) (not ranked) |
HDI (2003) | n/a Error: Invalid HDI value · n/a |
Owóníná | Euro (€) (EUR) |
Ibi àkókò | UTC-4 |
Àmì tẹlifóònù | 590 |
ISO 3166 code | MF |
Internet TLD | .mf assigned but not in use, .fr and .gp in use |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.