Chris Tucker
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Christopher "Chris" Tucker (born August 31, 1971)[1] je òṣeré ati aláwàdà ara ile Amerika, to gbajumo nitori isere re bi Detective James Carter ninu filmu alapameta Rush Hour ati bi Smokey ninu filmu odun 1995 Friday.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Chris Tucker | |
---|---|
![]() | |
Orúkọ àbísọ | Christopher Tucker |
Ìbí | 31 Oṣù Kẹjọ 1971 Atlanta, Georgia, U.S. |
Years active | 1988–present |
Genres | Comedy |
Ipa lọ́dọ̀ | Martin Lawrence |
Ipa lórí | Dave Chappelle |
Ibiìtakùn | http://www.christucker.com/ |
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.