Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Benedict Ayade (bíi ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1968) jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River tí wọ́n dìbò yàn wọlé ní Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n oṣù karún ọdún 2015, lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[1] Kí ó tó di gómìnà, ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[2]
Benedict Ayade | |
---|---|
Senator Ben Ayade Executive Governor, Cross River state | |
Governor of Cross River State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2015 | |
Lieutenant | Ivara Esu |
Asíwájú | Liyel Imoke |
Nigerian Senator for Cross River State | |
In office April 2011 – May 2015 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹta 1968 Kakum, Obudu LGA, Cross River State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Dr. Linda Ayade |
Website | www.senatorbenayade.org |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.