Asif Ali Zardari

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Pakistan From Wikipedia, the free encyclopedia

Asif Ali Zardari
Remove ads

Asif Ali Zardari (Urdu: آصف علی زرداری; Sindhi: آصف علي زرداري; ojoibi 26 July 1955) ni Aare ile Pakistan 11k lowolowo ati Abase-Alaga Egbe Awon Eniyan Pakistan (PPP). Zardari ni opó-kùnrin Benazir Bhutto, eni to je Alakoso Agba ile Pakistan ni emeji. Nigba ti iyawo re je didakupa ni Osu Kejila 2007, o di olori egbe PPP. Awon kan ti wi pe Zardari ni ikan larin awon olowojulo marun ni Pakistan pelu idiye iyi ohun ini to to US$1.8 billion (2005).[2][3]

Quick facts Ààrẹ ilẹ̀ Pakístàn, Alákóso Àgbà ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads