Anne Baxter
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Anne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kaarun ọdún 1923 , tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kéjììlá, oṣù kéjììlá, ọdún 1985.[2] Ó jẹ́ òṣèrébinrin to gba Ebun Akademi ti Obinrin Osere Keji Didarajulo nígbà áye rẹ̀.
Remove ads
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
Anne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje, oṣù kaarun ọdún 1923 ní ìlú Michigan, Indiana si idìlé Catherine Dorothy (née Wright; 1894–1979). Olúlú Westchester County, New York ni wón ti wo dàgbà.
Àwọn Ẹbùn ati Amì Ẹyẹ
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads