From Wikipedia, the free encyclopedia
Oba Akinsemoyin jẹ́ Oba Èkó láti ọdún 1704 sí 1749. Bàbá rẹ̀ ni Oba Ado, àwọn ẹbí rẹ̀ sì ni Erelu Kuti àti Oba Gabaro, ẹni tí ó jọba ṣáájú Akinsemoyin.[2]
Gégé bí Justice J. O. Kassim ṣe fi léde ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1978, ọmọ ọkùnrin mẹ́fà ni Akinsemoyin ní, orúkọ wọn ni, Sadeko, Amore/Olukokun, Abisako, Jolasun, Gbosebi àti Aina Egbe.[1]
Díè tí ó gbajúmọ̀ nínú àwọn ọmọ ọmọbìnrin Akinsemoyin ni: Onisiwo, Oniru, Oluwa, àti Akogun.[3][4][5]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.