Ibadan North-East (Yoruba: Ariwa-Ilaorun Ibadan) jẹ́ àgbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà. Olú ilẹ̀-iṣẹ́ wọn wá ní Ìwó Road. Àmì ọ̀rọ̀ ìfilẹ́tà ìránṣẹ́ sí tí agbègbè náà ni 200.[1]

Quick Facts Ibadan North-East Ariwa-Ilaorun Ibadan, Country ...
Ibadan North-East

Ariwa-Ilaorun Ibadan
Country Nigeria
StateOyo State
Government
  Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilIbrahim Akintayo (PDP)
Time zoneUTC+1 (WAT)
Close

Ìwọ̀n ilẹ̀

Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tí 18 km2 àti iye àwọn ènìyàn tó jẹ́ 330,399 ni ètò ìkànìyàn 2006.

Àwọn ìtọ́kasí

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.