From Wikipedia, the free encyclopedia
Argungu jẹ́ ilú kan ní Ipinle Kebbi ní orílè-èdè Naijiria. Ní ọdún 2007, ìlú náà ní èrò tó n h lọ bíi 47,064.[1]
Argungu | |
---|---|
LGA and town | |
Nickname(s): Gungun Nabame | |
Coordinates: 12°44′N 4°31′E | |
Country | Nigeria |
State | Kebbi State |
Government | |
• Sarkin Kabbi | Alhaji Samaila Muhammad Mera |
Population (2007) | |
• Total | 47,064 |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ọdún 1831 ni wọ́n kọ́ ilé Kanta Museum tí ó kọjú sí ọjà gbogboogbò ìlú náà. Wọ́n ń pe mùsíọ̀mù yìí lèyìn Muhammadu Kanta, tí ó ṣe ìdásílẹ̀ ìlú Kebbi ní ọdún 1515. [2]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.