Ìjọba ìbílẹ̀ Ọdẹ́dá

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ìjọba ìbílẹ̀ Ọdẹ́dámap

Ọdẹ́dá jẹ́ Ìjọba Ìbílẹ̀ àti ìletò kan ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú ilé-iṣẹ́ Ìjọba ìbílẹ̀ yí wà ní A5 highway7°13′00″N 3°31′00″E. Ìjọba ìbílẹ̀ yí ní ibùsọ tí ó 1,560 km² tí àwọn olùgbé ibẹ̀ sì tó 109,449 gẹ́gẹ́ bí étò ìkànìyàn ti ọdún 2006 ṣe fi lọ́ọ́lẹ̀. Ìjọba ìbílẹ̀ yí súnmọ́ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ́kípẹ́kí, tí ó sì pààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìlú Alọ̀gì.

Quick Facts Ọdẹ́dá, Country ...
Ọdẹ́dá
LGA and town
Motto(s): 
Ọdẹ́dá Gbayì
Thumb
Ọdẹ́dá
Ọdẹ́dá
Location in Nàìjíríà
Coordinates: 7°13′N 3°31′E
Country Nàìjíríà
StateÌpínlẹ̀ Ògùn
Government
  Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilSẹ̀míù Bọ́lá [1]
Area
  Total1,560 km2 (600 sq mi)
Population
 (2006 census)
  Total109,449
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
110
ISO 3166 codeNG.OG.OD
Close

Nọ́mbà ìfiránṣẹ́ (postal code) ìjọba ìbílẹ̀ yí 110.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.