![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/e/ec/Wale_Ojo_%2528cropped%2529.png/640px-Wale_Ojo_%2528cropped%2529.png&w=640&q=50)
Wale Ojo
Osere British-Nigeria / From Wikipedia, the free encyclopedia
Wale Ojo jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Britain. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣẹ láti ìgbà tó wà lọ́mọdé lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán. Ó tẹ̀síwájú láti máa ṣe eré ní UK àti Nàìjíríà.[1][2] Ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 1995 fún kíkópa tí ó kópa nínú fíìmù The Hard Case. Ó gba àmì ẹ̀yẹ fún òṣèrékùnrin tó dára jù lọ ní ọdún 2012 ní 2012 Nigeria Entertainment Awards.[3][4]
Ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ Wole Ojo.