From Wikipedia, the free encyclopedia
Vidiadhar Surajprasad Naipaul, TC (ojoibi 17 August 1932), to gbajuo bi V. S. Naipaul ati nigba miran bi Sir Vidia Naipaul, je olukowe ara Trinidad to je wa lati India to gbajumo fun awon iwe aroso re to dalori awon orile-ede tiundagbasoke. Fun awon ifihan ohun ti Akademi Swedin pe ni “awon itan adepamo,” Naipaul gba won Ebun Nobel fun Litireso ni 2001.[1] He has been called "a master of modern English prose."[2] O ti gba opolopo ebun alamookomooka, ninu won ni John Llewellyn Rhys Prize (1958), the Somerset Maugham Award (1960), the Hawthornden Prize (1964), the W. H. Smith Literary Award (1968), the Booker Prize (1971), ati David Cohen Prize fun ipa igbesiaye ninu Imookomooka Britani (1993).
V.S. Naipaul | |
---|---|
Iṣẹ́ | Novelist, essayist |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Trinidadian |
Genre | Novel |
Literary movement | Realism, Postcolonialism |
Notable works | A House for Mr. Biswas, A Bend in the River, The Enigma of Arrival, In A Free State |
Notable awards | Booker Prize 1971 Nobel Prize in Literature 2001 |
Ni 2008, The Times fi Naipaul sipo keje lori atojo won fun "Awon olukowe Britani 50 titobijulo lati 1945".[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.