Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Ahmadu Umaru Fintiri (ojoibi October 27, 1967) ni gomina Ipinle Adamawa lowolowo [1] O fi tele je omo ile Igbimo Asofin Ipinle Adamawa, nibi ti won ti yan gege bi Olori Ile Asofin. O di aropo gomina Ipinle Adamawa fun igba die leyin igba ti gomina Murtala Nyako je yiyokuro lori ipo na ni July 2014,[2][3] ko to gbepo na fun Bala James Ngilari leyin to lo osu meta lori ibe.[4]
Umaru Fintiri | |
---|---|
Governor of Adamawa State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 29, 2019 | |
Asíwájú | Bindo Jibrilla |
Acting Governor of Adamawa State | |
In office July 16, 2014 – October 1, 2014 | |
Asíwájú | Murtala Nyako |
Arọ́pò | Bala James Ngilari |
Speaker, Adamawa State Assembly | |
In office January 2014 – July 16, 2014 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | October 27, 1967 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party, PDP |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.