![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/9/98/Shubun_poster_Toshiro_Mifune.jpg/640px-Shubun_poster_Toshiro_Mifune.jpg&w=640&q=50)
Toshiro Mifune
From Wikipedia, the free encyclopedia
Toshiro Mifune (三船 敏郎 Mifune Toshirō Àdàkọ:IPA-ja; April 1, 1920 – December 24, 1997) jẹ́ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Japan Japan tó kópa nínú sinimá àgbéléwò tí iye rẹ̀ tó 170. Ó gbajúmọ̀ fún àwọn sinimá àgbéléwò tó ṣe pẹ̀lú olùdarí fíìmù Akira Kurosawa, láti 1948 dé 1965, nínú àwọn sinimá àgbéléwò bí Rashomon, Seven Samurai, Throne of Blood, ati Yojimbo. Bákan náà ó tún ṣe Musashi Miyamoto nínú sinimá àgbéléwò Hiroshi Inagaki tó ń jẹ́ Samurai Trilogy. [1] [2]
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Toshiro Mifune | |
---|---|
![]() Toshiro Mifune – detail from poster of the film Scandal (1950) | |
Ọjọ́ìbí | 三船 敏郎 (1920-04-01)Oṣù Kẹrin 1, 1920 Qingdao, China |
Aláìsí | December 24, 1997(1997-12-24) (ọmọ ọdún 77) Mitaka, Tokyo, Japan |
Orúkọ míràn | Sanchuan Minlang |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1947–1995 |
Olólùfẹ́ | Sachiko Yoshimine (1950–1995)(her death) |
Website | http://www.MifuneProductions.co.jp |
Close