Thomas Sankara
From Wikipedia, the free encyclopedia
Thomas Isidore Noël Sankara (December 21, 1949 – October 15, 1987) jẹ́ Ààrẹ àti olórí orílẹ̀-èdè Burkina Faso (tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ bi Upper Volta) láti 1983 dé 1987. Bákanná bó ṣe jẹ́ oníwà tófanimọ́ra, tí wọ́n gbógo fún nítorípé ó polongo ìlera àti ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin, ó tún kọjú ìjà bo ọ̀pọ̀ àwọn ìwà ìmọtaraẹninìkan ní Burkina Faso.[2] Ó jẹ́ lílé kúrò lórí ìtẹ́ ó sì jẹ́ fífikúpa nínú coup d'état tí Blaise Compaoré ṣe ní October 15, 1987, èyí tí wọ́n gbàgbọ́ pé ó wá látọwọ́ ìlẹ̀ Fransi.
Quick Facts 5th President of Upper Volta, Asíwájú ...
Thomas Isidore Noël Sankara | |
---|---|
5th President of Upper Volta | |
In office August 4, 1983 – August 4, 1984 | |
Asíwájú | Jean-Baptiste Ouédraogo |
Arọ́pò | None (country renamed to Burkina Faso) |
1st President of Burkina Faso | |
In office August 4, 1984 – October 15, 1987 | |
Asíwájú | None (country renamed from Upper Volta) |
Arọ́pò | Blaise Compaoré |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1949-12-21)Oṣù Kejìlá 21, 1949 Yako, Upper Volta (now Burkina Faso), French West Africa |
Aláìsí | October 15, 1987(1987-10-15) (ọmọ ọdún 37) Ouagadougou, Burkina Faso |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Burkinabé |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | none (military) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Mariam Sankara[1] |
Close