Stephanie Mills
From Wikipedia, the free encyclopedia
Stephanie Dorthea Mills[9][10] (ojoibi March 22, 1957)[1][11] je akorin, akoro-orin ati osere ara Amerika. Mills gbajumo nigba to kopa ninu ere oritage The Wiz gege bi "Dorothy" lati odun 1975 titi de 1977. Orin re, "Home" lati inu ere na di onipo kinni ni Amerika fun chart R&B ati ikan ninu awon orin re to gbajumo julo. Mills gba Ebun Grammy fun Akorin Obinrin R&B Didarajulo fun orin re "Never Knew Love Like This Before" ni odun 1981.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Stephanie Mills | |
---|---|
Mills on stage performing at the Detroit Opera House, April 2017. | |
Ọjọ́ìbí | Stephanie Dorthea Mills 22 Oṣù Kẹta 1957 (1957-03-22) (ọmọ ọdún 67)[1] Brooklyn, New York, U.S. |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1966–present |
Olólùfẹ́ | Jeffrey Daniel [2][3][4](m. 1980; div. 1983) Dino Meminger [5][6](m. 1989; div. 1991) Michael Saunders [7][8](m. 1993; div. 2001) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Labels |
|
Associated acts |
|
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |