![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/13/Song_Joong-ki_at_Style_Icon_Asia_2016.jpg/640px-Song_Joong-ki_at_Style_Icon_Asia_2016.jpg&w=640&q=50)
Song Joong Ki
From Wikipedia, the free encyclopedia
Song Joong-ki (tí wọ́n bí ní September 19, 1985) jẹ́ òṣẹ̀ré Gúsù Korea. Ó di gbajúmò nígbàtí ó ṣe eré orí-ìtàgé onítàn Sungkyunkwan Scandal (2010) àti orísìírísìí ère àtẹ̀léra Running Man (2010–2011) gẹ́gẹ́ bí ọkàn lára àwọn akópa. Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínú àwọn ère orí ẹ̀rọ amúhùnmáwòrán The Innocent Man (2012), Descendants of the Sun (2016), Arthdal Chronicles (2019), Vincenzo (2021), àti Reborn Rich (2022), pẹ̀lú àwọn fíìmù tó tàn kálẹ̀ A Werewolf Boy (2012), The Battleship Island (2017), àti Space Sweepers (2021).
Song Joong-ki | |||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
![]() Song in 2016 | |||||||||
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹ̀sán 1985 (1985-09-19) (ọmọ ọdún 38) Dong District, Daejeon, South Korea | ||||||||
Orílẹ̀-èdè | South Korean | ||||||||
Ẹ̀kọ́ | Sungkyunkwan University (BBA) | ||||||||
Iṣẹ́ | Actor | ||||||||
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present | ||||||||
Agent | HighZium StudioÀdàkọ:Efn-la | ||||||||
Olólùfẹ́ |
| ||||||||
Àwọn ọmọ | 1 | ||||||||
| |||||||||
Signature | |||||||||
![]() |
Song jẹ́ Gallup Korea's Television Actor of the Year ní 2012[1] àti ní 2017.[2] Òun ni a kọ́kọ́ fi kún àtò Forbes Korea Power Celebrity 2013 ní ipò keje,[3] Ó sì tún ṣe ipò kejì ní 2017, àti íkeje ní 2018.[4] Àṣeyọrí àwọn ère àtẹ̀léra amóhùnmáwòrán àti àwọn ìṣe fíìmù rẹ̀ fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ jákèjádò gẹ́gẹ́ bí orí Hallyu nínú ilé iṣẹ́ ìdárayá ti Korea. [5][6][7]