Sekhmet
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Other uses
Quick Facts Major cult center, Symbol ...
Sekhmet | |
---|---|
Script error: The module returned a nil value. It is supposed to return an export table. Sekhmet with head of lioness and a solar disk/sun disk and uraeus on her head | |
Major cult center | Memphis, Leontopolis |
Symbol | Sun disk, red linen, lioness |
Consort | Ptah |
Offspring | Nefertem |
Parents | Ra |
Close
Nínú Àwọn ìtàn-àkọọlẹ ara Egypt, Sekhmet ( /ˈsɛkˌmɛt/[1] tàbíSachmis ( /ˈsækmᵻs/), láti Àdàkọ:Lang-egy; Àdàkọ:Lang-cop), jẹ́ jagunjagun òrìṣà àti Oníṣègùn oogun òrìṣà. Sekhmet jẹ́ òrìṣà tí oòrùn, nígbà mìíràn à ń pè ní ọmọbìnrin tí òrìṣà Ra bí àti pé ó nigba mìíràn ó ní nkán ṣẹ pẹ̀lú àwọn òrìṣà Hathor àti Bastet.