Seal
From Wikipedia, the free encyclopedia
Henry Olusegun Adeola Samuel[3][4] (ọjọ́ìbí 19 February 1963), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ bíi Seal, ni akọrin àti olùdá-orin ará Brítánì.[5] Àwo orin rẹ̀ ti tà tó 20 millionu àwo orin káàkiri àgbáyé,[6] pẹ̀lú orin rẹ̀, "Crazy", tó gbéjáde ní ọdún 1991; àti "Kiss from a Rose", tó gbéjáde ní ọdún 1994.
Quick Facts Background information, Orúkọ àbísọ ...
Seal | |||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Seal in Sydney, 2012 | |||||||||||
Background information | |||||||||||
Orúkọ àbísọ | Henry Olusegun Adeola Samuel | ||||||||||
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Sealhenry Samuel[1][2] | ||||||||||
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejì 1963 (1963-02-19) (ọmọ ọdún 61) Paddington, London, England | ||||||||||
Irú orin | |||||||||||
Occupation(s) |
| ||||||||||
Years active | 1987–present | ||||||||||
Labels |
| ||||||||||
Associated acts |
| ||||||||||
|
Close