From Wikipedia, the free encyclopedia
San Juan (pípè /ˌsæn ˈwɑːn/, Pípè: [san ˈhwan], láti San Juan Bautista "Jòhánnù Onítèbomi Mímó") ní olúìlútitóbijùlo ní Puerto Rico. Juan Ponce da sílè ní odún 1521. Orúkọ áílándì ní Púẹ́rtò Ríkò, tí orúkọ ìlú s̀i jẹ San Juań. San Juan ní ibi gbóógì méta: San Juan àtijó, bííṣì àti agbègbè ríṣọ́ọ́tì àti bẹẹbè lọ. Óhun ni ó tóbi jù ní ààrin gùngùn Áílándì tí ó ní ilé iṣẹ́ bíi: epo rọ̀bì àti `súgà, ilé ìpọtín, síméntì,apo ògùn òyì́nbó,Ilé isé irin, aṣo àti tábà.
San Juan, Puerto Rico | |||
---|---|---|---|
| |||
Nickname(s): La Ciudad Amurallada (The Walled City) | |||
Location of San Juan within the island of Puerto Rico | |||
Country | United States | ||
Territory | Puerto Rico | ||
Wards (barrios) | 18 | ||
Founded | 1508/1521 | ||
Government | |||
• Mayor | Jorge A. Santini Padilla (PNP) | ||
• Senatorial dist. | 1 - San Juan/Guaynabo | ||
• House dist. | 1,2,3,4,5 | ||
Area | |||
• City | Àdàkọ:Infobox settlement/impus/mag | ||
• Land | 47.82 sq mi (123.9 km2) | ||
• Water | 29.11 sq mi (75.4 km2) 37.8% | ||
Population (2008)[1] | |||
• City | 422,665 | ||
• Density | 8,838.7/sq mi (3,412.6/km2) | ||
• Metro | 2,509,007 | ||
• Gentilic | Sanjuaneros | ||
• Racial groups (2000 Census)[2] | 72.7% White 11.9% Black 0.5% American Indian/AN 0.5% Asian 0.0% Native Hawaiian/PI 9.1% Some other race 5.4% Two or more races | ||
Time zone | UTC-4 (AST) | ||
Anthem | "La Borinqueña" | ||
Website | www.sanjuancapital.com gobierno.pr |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.