Rita Hayworth
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Rita Hayworth tí orúko àbísọ rẹ̀ jẹ́Margarita Carmen Cansino; ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1918, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1987 (October 17th, 1918– May 14, 1987) jẹ́ òṣeré ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Rita Hayworth | |
---|---|
Rita Hayworth 1942 | |
Ọjọ́ìbí | Margarita Carmen Cansino Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1918 (October 17, 1918) Ìpínlẹ̀ New York, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà |
Aláìsí | ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1987 May 14, 1987(1987-05-14) (ọmọ ọdún 68) New York, I.A.A. |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Amẹ́ríkà |
Orúkọ míràn | Rita Cansino |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 1934–1972 |
Olólùfẹ́ | Edward C. Judson (1937-1942) Orson Welles (1943-1948) Aly Khan (1949-1953) Dick Haymes (1953-1955) James Hill (1958-1961) |
Parent(s) | Eduardo Cansino (deceased) Volga Hayworth (deceased) |
Close