Paul Dirac
From Wikipedia, the free encyclopedia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Paul Adrien Maurice Dirac, OM, FRS (pípè /dɪˈræk/ di-RAK; 8 August 1902 – 20 October 1984) je onimofisiiki oniro ara Britani. Dirac se afikun pataki si ibere isise ero ayosere ati agbaraonina ayosere. O di ipo Ojogbon Aga Lukas fun Mathematiiki mu ni Yunifasiti ilu Cambridge, o si lo odun merinla togbeyin laye re ni Florida State University.
Paul Adrien Maurice Dirac | |
---|---|
Ìbí | Paul Adrien Maurice Dirac 8 Oṣù Kẹjọ 1902 Bristol, England |
Aláìsí | 20 October 1984 ọdún 82) Tallahassee, Florida, USA | (ọmọ
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United Kingdom |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Cambridge University Florida State University |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Bristol Cambridge University |
Doctoral advisor | Ralph Fowler |
Doctoral students | Homi Bhabha Harish Chandra Mehrotra Dennis Sciama Behram Kurşunoğlu John Polkinghorne |
Ó gbajúmọ̀ fún | Dirac equation Dirac comb Dirac delta function Fermi–Dirac statistics Dirac sea Dirac spinor Dirac measure Bra-ket notation Dirac adjoint Dirac large numbers hypothesis Dirac fermion Dirac string Dirac algebra Dirac operator Abraham-Lorentz-Dirac force Dirac bracket Fermi–Dirac integral Negative probability Dirac Picture Dirac-Coulomb-Breit Equation |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1933) |
Religious stance | Atheist [1] |
Notes He is the stepfather of Gabriel Andrew Dirac. |
Ninu awon awari re, o sagbekale isodogba Dirac, eyi salaye iwuwa awon fermion eyi lo si faye gba isotele wiwa olodi elo.
Dirac pin Ebun Nobel ninu Fisiksi fun 1933 pelu Erwin Schrödinger, "fun sisawari awon iru iro atomu tuntun to wulo."[2]
Paul Dirac je bibi ni ilu Bristol,[3] Ilegeesi, ni adugbo Bishopston lo gbe dagba.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.