![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b6/Queen_Elizabeth_II_in_March_2015.jpg/640px-Queen_Elizabeth_II_in_March_2015.jpg&w=640&q=50)
Olórí orílẹ̀-èdè
òṣìṣẹ́ ìjọba tó ní ipò aláṣẹ tó gajùlọ ní orílẹ̀-èdè òmìnira / From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Politics sidebar Olórí orílẹ̀-èdè ni ẹni aráàlú kan tí óún dúró fún orílẹ̀ ìjọba kan lábẹ́ àṣẹ[1] ní ìṣọ̀kan àti lábẹ́ òfin rẹ̀. Bí irú ìjọba àti ìpín àwọn agbára ìjọba orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan bá ṣe rí, olórí orílẹ̀-èdè le jẹ́ fún oyè lásán tàbí lẹ́ẹ̀kannáà bíi olórí ìjọba àti ìṣẹ́ míràn.
Àwọn olórí orílẹ̀-èdè àwọn orísirísi orílẹ̀-èdè:
- Emmanuel Macron, Ààrẹ ilẹ̀ Fránsì
- Ram Nath Kovind, Ààrẹ ilẹ̀ Índíà
- Joe Biden, Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
- Moon Jae-in, Ààrẹ ilẹ̀ Kòréà Gúúsù
- Elizabeth II, Ọba ilẹ̀ Brítánì
- Jair Bolsonaro, Ààrẹ ilẹ̀ Brasil
- Muhammadu Buhari, Ààrẹ ilẹ̀ Náìjíríà
- Halimah Yacob, Ààrẹ ilẹ̀ Síngápọ̀
- Vladimir Putin, Ààrẹ ilẹ̀ Rọ́síà